HYMN 403

S.S 263 (FE 426)
"Ro mo Bibeli” - Ps. 119:105


1.  RO mo Bibeli b'a gb’awon nkan 'yoku

     Ma so ilana‘re t’o sowon nu

     Ihin re nji gbogbo okan ti ntogbe 

     Ileri re nso oku d‘alaye.

Egbe:  Ro mo Bibeli Ro ma Bibeli!

           Ro mo Bibeli! mole f ’ese wa.


2.  Ro mo Bibeli! Oro ‘yebiye yi 

     O nfi ‘ye ainipekun f’ araiye 

     O ni ‘ye ainipekun f‘araiye

     O ni 'ye lori ju b‘eda ti ro lo 

     Wa ibukun Re nigba t’a le ri! 

Egbe:  Ro mo Bibeli Ro ma Bibeli!...


3.  Fitila f’eniti o ti sako lo 

     Amona fun Odo ti 'ba subu 

     Reti elese t’aiye re ti baje 

     Opa f'agba, Iwe didara julo!

Egbe:  Ro mo Bibeli Ro ma Bibeli!

           Ro mo Bibeli! mole f ’ese wa.  Amin

English »

Update Hymn