HYMN 393

O.t.H.C 136 C.M (FE 416)
"Oruko re ni Iyanu" - Isa 9:6



1.  OLORUN Olodumare 

     Baba, Omo, Emi 

     Riri enit'a ko le mo 

     Eniti‘a ko Ie ri.


2.  Ye! Baba Olodumare 

     K‘a wariri fun O

     Ni gbogbo orile ede 

     Li a o ma sin O.


3.  Olorun omo, Ore wa 

     Wo t'o ra wa pada 

     Ma jowo wa, Olugbala! 

     Gba wa patapata.


4.  A! Olorun Emi Mimo 

     ‘Wo olore‐ofe

     A be O, fun wa ni imo 

     K'a m'Olorun n'ife.


5.  Okansoso sugbon meta 

     Eni Metalokan

     Olorun awamaridi 

     Eni Metalokan.  Amin

English »

Update Hymn