HYMN 390

O. t. H.C 97 7s (FE 413)
“Ogo ni fun Olorun li oke orun"
- Luku 2:14



1.  E fi ogo fun baba

     Nipa Eniti a wa

     O ngbo adura wa 

     O nf'eti si orin won.


2.  E fi ego fun Omo

     Kristi, ‘Wo ni Oba wa 

     E wa e korin s‘oke 

     S'Odaguntan elese.


3.  Ogo fun Emi Mimo

     Bi ojo Pentikosti

     Ru aiya awon ewe 

     F’orin mimo s'ete won.


4.  Ogo ni l‘oke orun 

     Fun Eni Metalokan 

     Nitori ihin rere

     Ati ife Olorun.  Amin

English »

Update Hymn