HYMN 380

C.M.S 274. o.t.H.C 224, 7s (FE 401)
"On o si fun nyin Ii Olutunu miran ki o 
ma banyin gbe titi Iai" - John 14:16



1.  EMl Mimo sokale 

     Ba wa gbe ni aiye yi 

     Fi ohun orun han ni

     Si ba ni sin Olorun.


2.  Ese wa ni okan wa

     Ti a ko le fi sile 

     Agbara wa ko to se

     Bi “Wo ko ba pelu wa".


3.  Awa nfe k’ese parun 

     L’okan ati l'ara wa 

     Wa, Emi Mimo, jo wa 

     Ko we gbogbo ese nu.


4.  Olorun, 'Wo l'awa nfe

     Fi Emi Re na fun wa

     K'a le pa ofin Re mo 

     K’a si rin ni one Re.  Amin

English »

Update Hymn