HYMN 38

C.M.S. 37, H.C 222, L.M. (FE 55) 
“Nitori, Iwo Oluwa, Ii o ti mu mi
yo nipa ise Re" - Ps. 92:4


1.  DlDUN n‘ise na, Oba mi 

     Lati ma yin Oruko Re; 

     Lati se ‘fe Re l'owuro 

     Lati so oro Re l'ale.


2.  Didun l’ojo ‘simi mimo 

     Lala ko so fun mi loni 

     Okan mi ma korin iyin 

     Bi harpu Dafidi didun.


3.  Okan mi o yo n'Oluwa 

     Y'o yin ise at’oro Re, 

     lse ore Re ti po to! 

     ljinle si ni imo Re.


4.  Emi o yan ipo ola 

     Gb‘ore-ofe ba we mi nu 

     Ti ayo pupo si ba mi, 

     Ayo mimo lat' oke wa.


5.  "Ghana, ngo ri, ngo gbo ngo mo, 

     Ohun gbogbo ti mo ti nfe 

     Gbogbo ipa mi y'o dalu

     Lati se ‘fe Re titi lai.  Amin


English »

Update Hymn