HYMN 379

C.M.S 273 H.C 595 (FE 400)
"O mi i won, O ni e gba Emi Mimo”
- Job. 20:22 
Tune: Bi mo ti ri



1.  WA mi si wa, Emi Mimo 

     Tan ‘na orun si okan wa 

     Emi af’ororo yan ‘ni

     Ti f’emi meje re funni.


2.  lse nla Re at‘oke wa 

     N‘itunu, iye, ina ife 

     F‘imole Re igbagbogbo 

     Le okunkun okan wa lo.


3.  F'ororo ore-ofe Re 

     Pa oju eri wa ko dan

     L‘ota jina s'ibugbe wa 

     lre n’igbe ‘biti ‘Wo nso.


4.  Ko wa k'a mo Baba, Omo

     Pelu Re l’okansoso

     Titi aiye ainipekun

     Ni k‘eyi ma je orin wa.  Amin

English »

Update Hymn