HYMN 371

1.  OJO nla kan n bO wa 

     Ojo nla kan n bo

     Ojo nla kan bo wa nigboose

     T’awon eniyan mimo at'elese 

     yoo pinya lwo ha setan fun ojo naa.

Egbe:  O ha setan? O ha setan

            O ha setan fun ojo 'daju

            O ha setan? O ha setan

            Fun ojo nla naa.


2.  Ojo didan kan n be 

     Ojo naa n bo wa

     Ojo didan kan n bo nigbaoose 

     Sugbon didan re je ti awon t'o 

     fe Oluwa lwo ha setan fun ojo naa.

Egbe:  O ha setan? O ha setan...


3.  Ojo ‘banuje n bo

     Ojo naa n bo wa

     Ojo ‘banuje n bo nigboose 

     T’elese yio gbo pe, E to, Emi ko 

     mo yin ri

     Iwo ha setan fun ojo naa.

Egbe:  O ha setan? O ha setan

            O ha setan fun ojo 'daju

            O ha setan? O ha setan

            Fun ojo nla naa.  Amin

English »

Update Hymn