HYMN 367

(FE 389)
C.M.S 417, H.C 400 C.M
“Idile kan Ii orun ati Ii aiye" Efe 3:15



1.  WA k’a da m’awon ore wa 

     Ti nwon ti jere na

     N’ife k'a okan ba won lo 

     S’ode orun lohun.


2.  K’awon t‘aiye dorin won mo 

     T’awon to lo s’ogo

     Awa l’aiye, awon l‘orun 

     Okan ni gbogbo wa.


3.  ldile kan n’nu Krist’ ni wa 
 
      Ajo kan l'a si je

      lsan omi kan lo ya wa 

      lsan omi iku.


4.  Egbe ogun kan t‘Olorun 

     Ase Re l‘a si nse

     Apakan ti wo'do na ja 

     Apakan nwo lowo!


5.  Emi wa fere dapo na

     Y‘o gb‘Ade bi tiwon

     A o yo s’ami Balogun wa 

     Lati gbo ipe Re.


6.  Jesu, so wa, s‘amona wa

     Gba' oniko ba de 

     Oluwa pin omi meji

     Mu wa gunle I‘ayo.  Amin

English »

Update Hymn