HYMN 362

CM (FE 384)

     

1.  E GBO b‘awon Angeli ti 

     Nfi Ogo f'Olorun

     Ati awon Olus‘Agutan 

     Nfi ‘yin fun U,

2.  Gbogbo ogun orun pelu 

     Agba mejila

     Kerubu pelu Serafu 

     Nfi ‘yin fun U.


3.  Oke meje at'egbaji 

     Awon Agba woli

     Awon t’o nfe l’Olugbala 

     Nf ‘yin fun U.


4.  Gbogbo’Ogun orun, e ho ye

      Aiye gbo iro na,

      Imisi Emi ba le wa 

      Awa nyin I.


5.  N’torina awa Kerubu 

     Ati Serafu 

     Ninu aginju aiye yi 

     Nyin Baba.


6.  Ogo fun Baba Olore 

     Ogo f’Omo Re

     Ogo ni fun Emi Mimo 

     Loke Orun.  Amin

English »

Update Hymn