HYMN 360

(FE 382)
C.M.S 418 t. H.C 585
"Ewe ati agba duro niwaju Olorun" 
- Ifi 20:12 
Tune: Baba mi gba mba Nsako lo



1.  A WA f ’ori bale/fun O Jesu

    ‘Wo ti s’Olori ljo awon/enia re, 

    ljo ti nibe laiye yi, a/ti lo/run 

    pelu Alleluya!


2.  ‘Wo t‘o ku to si jin/de fun wa

     T’o mbe lodo Baba bi Ala/gbawi 

     wa K’ogo at’olanla/je Tire

     Alleluya!


3.  Ati li ojo nla Pen/tikosti

     Ti o ran Parakliti/si aiye 

    Olutunu nla re ti/mba wa 

    gbe; Alleluya!


4.  Lat’ori ite Re lo/ke orun

     L’O si nwo gbogbo awon 

     o/jise Re T'o si nsike gbogbo 

     awon Aje/ riku Re. Alleluya!


5.  A fi iyin at‘olanla f’o/oruko Re, 

     N'tori iku gbogbo awon o/jise Re,

     Ni gbogbo ile! A/gbaye yi 

     Alleluya!  Amin

English »

Update Hymn