HYMN 356

C.M.S 422, K. (FE 379) 
306 t.H.C 106 6. 7s
"Kiyesi i, iru ife ti Baba fi fun wa pe 
ki a Ie ma pe wa li omo Olorun"
- 1John 3:1




1.  ALABUKUN n'nu Jesu 

     Ni awon om'Olorun

     Ti a fi eje re ra

     Lat’ inu iku s'iye.

Egbe:  A ba je ka wa mo won

           L'aiye yi, ati I'orun.


2.  Awon ti a da l'are 

     Nipa ore-ofe Re

     A we gbogbo ese won 

     Nwon o bo lojo ‘dajo.

Egbe:  A ba je ka wa mo...


3.  Nwon s‘eso ore-ofe

     Ninu ise ododo

     Irira l‘ese si won 

     Or'Olorun ngbe ‘nu won.

Egbe:  A ba je ka wa mo...


4.  Nipa Ej'Odagutan 

     Nwon mba Olorun kegbe

     Pelu Ola-nla Jesus

     A wo won l'aso ago.

Egbe:  A ba je ka wa mo won

           L'aiye yi, ati I'orun.  Amin

English »

Update Hymn