HYMN 355

1.  Gba ti ipe Oluwa ba dun t‘aye yoo 

     si fo lo Ti imole ojo titun yoo si de

     Nigba ti awon omo igbala ba pejo l'oke 

     T’a ba si p‘oruko lohun, n o wa n’be.

Egbe:  Gba t'a ba p’oruko lohun 

           Gba t'a ba p’oruko Iohun 

           Gba t'a ba p'oruko lohun

           Gba t’a ba p'oruko Iohun

           n o wa n’be.

2.  L'ooro ayo naa t‘awon oku n‘nu 

     Kristi yoo jide

     Ti won yoo si pin n‘nu ogo ajinde

     Gba ti awon ayanfe yoo pejo 

     si oke orun T‘a ba si p‘oruko 

     l‘ohun, n o wa n'be.

Egbe: Gba t'a ba p'oruko lohun...


3.  Je ki a fi gbogbo akoko wa s'ise 

     f'Oluwa. Jeki a rohin ife iyanu Re

     Nigba ti a ba si pari ire-ije wa l’aye 

     T'a ba si p’oruko l’ohun, n o wa n'be

Egbe:  Gba t'a ba p’oruko lohun 

           Gba t'a ba p’oruko Iohun 

           Gba t'a ba p'oruko lohun

           Gba t’a ba p'oruko Iohun

           n o wa n’be.  Amin

English »

Update Hymn