HYMN 353

(FE376)
CM.S 425. H.C 560 C.M
"Opolopo enia ti enikeni ko le ka 
iye duro niwaju ite” - Ifi. 7:9



1.  E WA k’a da orin wa po 

     Mo t‘awon Angeli 

     Egbegberun ni ohun won 

     Okan ni ayo won.


2.  Nwon nkorin pe, ‘Ola-nla ye 

     Od-agutan t'a pa

     K’a agberin pe “Ola-nla ye" 

     Tori O ku fun wa.


3.  Jesu, li O ye lati gba

     Ola at’agbara 

     K’iyin t’enu wa ko le gba 

     Je Tire, Oluwa.


4.  K'awon t’o wa loke orun 

     At’ile at'okun

     Dapo lati gb'ogo Re ga 

     Jumo yin ola Re.


5.  Ki gbogbo eda d'ohun po 

     Lati yin oruko

     Enit’ o joko lor’ite 

     Ki nwon si wole fun.  Amin

English »

Update Hymn