HYMN 344

(FE 367)
C.M.S 243 H.C 280 H.C 78 D 7s
"lwo ti goke si ibi giga" - Ps. 68:18



1.  KRISTI, lehin isugun 

     lwo ti goke lo 

     Kerubu at’ogun-orun 

     Wa sin O goke lo 

     K'aiye so ‘tan na jade 

     Emmanueli wa

     Ti s‘ara iy’ara wa 

     G’or‘ite Baba.


2.  Nibe l'O duro, t‘O nso 

     Agbara eje Re

     O mbebe fun elese 

     “Wo Alagbawi wa 

     Gbogbo ayidayida 

     T’ayo, t’aniyan wa, 

     N’lwo nse iyonu si 

     T'lwo si mbebe fun.


3.  Nitori itoye nla

     Ti agbelebu Re

     K’O fi Emi Re fun wa 

     So ofo wa d’ere

     Titi nipa iyanu

     Okan wa o goke

     Lati ba O gbe titi

     Li ayo ailopin.  Amin

English »

Update Hymn