HYMN 329

(FE 352)
C.M.S 230 t. H.C 577 6s. 4s
“Awon oba aiye kese jo ati awon ijoye 
ngbimo po si Oluwa" - Ps. 2:2



1.  B‘ELESE s'owo po

     Ti nwon nde s’Oluwa 

     Dimo si Kristi Re 

     Lati gan Oba na 

     B’aiye nsata

     Pelu Esu, Eke ni nwon 

     Nwon nse lasan.


2.  Olugbala joba!

     Lori oke Sion 

     Ase ti Oluwa 

    Gbe Omo Tire ro 

     Lati ‘boji

     O ni, k‘ O nde 

     K' O si goke 

     K' O gba ni la.


3.  F’eru sin Oluwa 

     Si bowo f 'ase Re 

     F'ayo wa sodo Re 

     F’ iwariri duro

     E kunle fun 

     K'e teriba

     So t‘ipa Re

     Ki omo na.  Amin

English »

Update Hymn