HYMN 328

(FE 351)
K. 160 5t.S 747 88.6.
Wo ti di igbekun ni igbekun le"
- Ps. 68:18



1.  JESU t'o ku, k'o gb’aiye la 

     Jinde kuro ninu oku

     Nipa agbara re

     A da sile lowo iku

     O d'igbekun n'igbekun Io 

     O ye, k‘o ma ku mo.


2.  Enyin om'OIorun, e wo 

     Olugbala ninu ogo

     O ti segun iku

     Ma banuje maberu mo 
  
     O nlo pese aiye fun nyin 

     Yio mu yin lo ‘Ie.


3.  O f’oju anu at'ife

     Wo awon ti O ra pada 

     Awon ni ayo Re

     O ri ayo at‘ise won

     O bebe ki nwon le segun 

     Ki nwon ba joba lai.  Amin

English »

Update Hymn