HYMN 326

(FE 349) K.184. t. H.C 258. S.M 
"Kristi ti jinde kuro ninu oku"
- 1Kor. 15:20



1.  OLUWA ji l’oto

     lhin na ha s‘oto

     Nwon ti ri p‘Olugbala ku

     Nwon ri l'aye pelu.


2.  Oluwa ji l’oto

     Oto ko fe ju yi

     Anu at‘otito pade 

     Ti nwon ti ns‘ota ri.


3.  Oluwa ji l‘oto"

     lse Re l‘ose tan

     A da ide onigbowo

     A se apa iku.


4.  ‘Oluwa ji l‘oto 

     Boji ko le se mo

     Awon t‘o ku si ji pelu 

     Nwon ki o si ku mo.  Amin

English »

Update Hymn