HYMN 315

H.C. 202 t. 449 6. 7s. (FE 338)
Tune: Apata Aiyeraiye.
“Je ki a se lala lati wo inu isimi na."
 - Heb. 4:11



1.  ISIMI awon mimo,

     Ojo ohun ijinle,

     Apere isimi Re,

     Oluwa simi 'se Re,

     O ya 'jo na si mimo.


2.  Loni oku Oluwa, 

     Nsimi ninu iboji; 
  
     A ti we l’ aso oku, 

     Lat' ori titi d'ese, 

     A si fi okuta se, 

     A si ti edidi di.


3.  Oluwa, titi aiye,

     L' a o ma pa eyi mo, 

     A’ o t’ ilekun pinpin, 

     K' ariwo ma ba wole,

     A o fi suru duro, 

     Tit’ lwo o tun pada.


4.  Gbogbo awon t’ o ti sun, 

      Nwon o wa ba O simi; 

      Nwon o bo lowo lala, 

      Nwon nreti ipe ‘kehin, 

      T' a o di eda titun,

      T' ayo wa ki y’o l' opin.


5.  Jesu yo wa nin’ ese

     K’ a ba le ba won wole,

     Ewu ati ‘se y’ o tan,

     A o f' ayo goke Io,

     A o ri Olorun wa,

     A o si ma sin lailai.  Amin

English »

Update Hymn