HYMN 302

1.  LORI oke lehin 'lu  l‘agbelebu 

     kan wa 

     Apere iya at‘egan

    Okan mi fa sibe, s’Olufe mi owon 

    T‘a pa f’ese gbogbo aye.

Egbe:  Emi yoo gbe agbelelu re 

            Titi n fo fi pari ajo mi

            Emi o ro m agbelebu naa 

            K’emi le de ade n'ikehin.


2.  Agbelebu naa t’awon araye kegan 

     Oun l'o ni ewa l‘oju mi,

     ‘Tori Om’Olorun, bo ogo Re sile 

     O si ti ru u lo si Kalfari.

Egbe:  Emi yoo gbe agbelelu re...


3.  L'ar'agbelebu naa, t'eje mimo 

     san si 

     Mo r‘ewa iyanu nibe

     Tori pe lori re, Jesu jiya o ku

     O dariji, o we mi mo.

Egbe:  Emi yoo gbe agbelelu re...


4.  Emi yoo j’olooto s’Emiti t’O 

     ku fun mi 

     Ngo f’ayo r’egan oun tiju

     Nigboose yoo pe mi lo le ayeraye

     Ki n le n‘ipin ninu ogo Re.

Egbe:  Emi yoo gbe agbelelu re 

            Titi n fo fi pari ajo mi

            Emi o ro m agbelebu naa 

            K’emi le de ade n'ikehin.  Amin

English »

Update Hymn