HYMN 294

(FE 315) HC 184 t. H.C 2nd
Ed 165 D. 8s 7s
"On a ru aisedede won" - Isa. 53:11



1.  W‘OLORI Alufa Giga

     B'o ti gbe ebe wa lo 

     L‘ogba, o f 'ikedun wole 

     O f'eru dojubole 

     Angeli f’idamu duro 

     Lati ri Eleda be

     Awa o ha wa l’aigbogbe 

     T’a mo pe tori wa ni?


2.  Kiki eje Jesu nikan

     L'ole yi oka pada

     On I‘o le gba wa n’nu ebi 

     On l’o le m’okan wa ro 

     Ofin at‘ikilo ko to

     Nwon ko si le nikan se 

     Ero yi l'o le m'okan ro 

     Oluwa ku dipo mi!


3.  Jesu, gbogbo itunu wa 

     Lat‘odo Re l’o ti nwa

     lfe, ‘gbagbo, reti, suru 

     Gbogbo re I'eje Re ra 

     LAt’ inu ekun Re l'a ngba 

     A ko da ohun kan ni

     Lofe n’Iwo nfi won tore

     Fun awon t‘o s’ alaini.  Amin

English »

Update Hymn