HYMN 292

t.H.C. 233 C.M (FE 313) 
"lhinrere kristi agbara Olorun nmi
si igbala” - Rom. 1:16



1.  KRIST t‘agbelebu l’orin wa, 

     ljinle t’awa nso

     O j’egan loju awon ju 

     Were lowo Griki.


2.  Sugbon okan t'Olorun ko 

     F‘ayo gba oro na

     Nwon ri ogbon, ipa, ife 

     T’o han n’Oluwa won.


3.  Adun, oruko Re yiye

     Mu soji s’okan won 

     Aigbagbo l’ohun t'o ba ni je 

     Si ebi at’iku.


4.  Lai j'OIorun t‘o or‘ofe ka 

     Bi owara ojo

     Lasan l‘Apollos funrugbin 

     Paul si le gbin lasan.  Amin

English »

Update Hymn