HYMN 290

C.M.S 193 K. 241 t.H.C 16, L.M
(FE 311)
'O ye ki a se ariya, ki a si yo"
- Luku 15:22



1.  TANl le so t‘ayo ti mbe 

     Ni agbala Paradise 

     Gba t‘amusua ba pada 

     T‘o si di arole ogo?


2.  Ni ayo ni Baba fi wo 

     Eso ife Re ailopin 

     L’ayo l'Omo we Ie t’O ri 

     Ere iwaya-ija Re.


3.  Tayotayo l’Emi si nwo 

     Okan mimo t'o n so dotun 

      Awon mimo at‘Angel nko 

     Orin Igbala Oba won.  Amin

English »

Update Hymn