HYMN 29

C.M.S. t.H.C. 68, S.M (FE 46) 
“Ranti ojo isimi lati Io o ni mimo"
- Eks 20:8


1.  OLORUN wa own,
     
     T'o fi ojo mefa

     Da nkan ghogho ti mbe laiye, 

     Simi nijo keje.


2.  O pase k‘a bowo 

     Fun ojo isimi, 

     lbunu Re tobi pupo 

     S‘awon t'o o rufin yi.


3.  Awon baba nla wa

    Ti ku nin'okunkun; 

    Nwon je ogbo aborisa 

    Nwon ko mo ofin Re.


4.  Awa de, Oluwa 

    Gege bi ase Re, 

    Lehin ise ijo mefa, 

    Lati se ife Re.


5.  Mimo l’ojo oni,

     O ye ki a simi

     K’a pejo ninu ile Re 

     K’a gbo 'ro mimo Re.


6.  lsimi nla kan ku 

     F'awon enia Re, 

     Om’Olorun, Alabukun 

     Mu wa de ‘simi re!  Amin

English »

Update Hymn