HYMN 280

T.H.C. 150 C.M (FE 300) 
"Gbo adura mi Oluwa" - Ps.102:1



1.  BABA alanu t'o fe wa 

     Mo gb’okan mi si O

     lpa Re t’o po l'o gba wa; 

     Awa nkorin si O.


2.  Tire papa l’awa fe ese 

     Gb’okan wa fun ebo; 

     O da wa, o si tun wa bi 

     A f' ara wa fun O.


3.  Emi Mimo, wa sodo mi, 

     F'ife Oluwa han

     Fun mi k‘emi k’o le ma rin 

     N’ife Oluwa mi.  Amin

English »

Update Hymn