HYMN 277

H.C 117 6s (FE 297)
“ljoba re de" - Matt. 6:10



1.  KRIST’ ki 'joba Re de 

     Ki ase Re bere

     F’opa-irin Re fo 

     Gbogbo ipa ese.


2.  ljoba ife da

     Ati t'alafia

     Gba wo ni irira 

     Yio tan bi t'orun?


3.  Akoko na ha da 

     T’ote yio pari 

     lka at‘ireje 

     Pelu ifekufe?


4.  Oluwa jo, dide

     Wa n’nu aghara Re

     Fi ayo fun awa 

     Ti o ns‘aferi Re.


5.  Eda ngan oko Re 

     Koko nje agbo Re 

     lwa ‘tiju pupo 

     Nfihan pe ‘fe tutu.


6.  Okun bole sibe 

     Ni ile keferi

     Dide 'Rawo oro

     Dide, mase wo mo.  Amin

English »

Update Hymn