HYMN 266

S.124 t.H.C 336 11s (FE 286)
"Ikilo meta - Ma ba ja, ma bi ninu 
ma pa ina Emi" - 1 Tess. 5:19



1.  lWO elese, Emi nfi anu pe 

     Okan re t‘o ti yigbi ninu ese 

     Ma se ba Emi ja, ma pe titi mo 

     Ebe Olorun re Ie pari loni.


2.  Omo Ijoba, mas'eru ese mo; 

     Gb’ebun Emi Mimo ati itunu 

     Ma bi Emi ninu, Oluko re ni 

     K’a ba le se Olugbala re logo.


3.  Tempili d'ibaje ewa re d‘ile

     lna pepe Olorun fere ku tan

     Bi a fi ife da, O si le tun ran 

     Mase pa ‘na Emi, Oluwa mbo wa.  Amin

English »

Update Hymn