HYMN 265

H.C. 172 t.S 56 8s 7s. 3 (FE285)
"Ojo ibukun o si ro” - Esek. 34:26



1.  Oluwa mo gbo pe, Iwo 

     Nro ojo ‘bukun kiri 

     ltunu fun okan are

     Ro ojo na sori mi.

Egbe:  An emi, an’emi 

           Ro ojo na sori mi.


2.  Ma koja Baba Olore 

     Bi ese mi tile po

     Wo le fi mi sile sugbon 

     Je k’anu Re ba le mi. 

Egbe:  An emi, an’emi...


3.  Ma koja mi, Olugbala 

     Je k'emi le ro mo o 

     Emi nwa oju rere Re 

     Pe mi mo awon t’o npe. 

Egbe:  An emi, an’emi...


4.  Mo koja mi, Emi Mimo 

     Wo le la ‘ju afoju

     Eleri itoye Jesu

     Soro as na si mi.

Egbe:  An emi, an’emi...


5.  Mo ti sun fonfon nin’ese 

     Mo bi O ninu koja

     Aiye ti de okan mi jo

    Tu mi k'o dafiji mi. 

Egbe:  An emi, an’emi...


6.  lfe Olorun ti ki ye

     Eje kristi iyebiye

     Ore-Ofe alainiwon

     Gbe gbogbo re ga n'nu mi. 

Egbe:  An emi, an’emi...


7.  Ma koja, mi dariji mi

     Fa mi mora, Oluwa

     “Gba o nf’ibukun f'elomi, 

     Masai f‘ibukun fun mi.

Egbe:  An emi, an’emi 

           Ro ojo na sori mi.  Amin

English »

Update Hymn