HYMN 262

C.M.S.188 H.C. 173 L.M (FE 282)
“E tetilele, ki e si wa si odo mi, e
gbo, okan nyin o si ye" - Isa. 55:3



1.  OLORUN, Baba mi, Wo npe

     Asako omo Re mora?

     Iwo o ha dariji mi?

     Mo de, mo de, jo gba mi la.


2.  A! Jesu, Iwo nrekoja
    
     Pelu ore at‘agbara?

     'Wo ko ha ngbo igbe mi?

     Mo de, mo de, sanu fun mi.


3.  A! Emi Mimo Iwo ni?

    Ore ti mo ti sati pe!

    Wo ha mbebe fun mi sibe?

    Mo de, mo de, m'ailera le.


4.  Mo de, Oluwa, ife Re

     Ni o nro mi t'o si nfa mi

    Mo wole lese re, ki nmo

    B'o ti dun lati je Tire.  Amin

English »

Update Hymn