HYMN 256

C.M.S. 172 H.C 159 8s.6.9 (FE 276)
“Enikeni ti o to mi wa, emi ki yio 
ta nu bi o ti wu ki o ri" - John 6:37




1.  BI mo ti ri laisawawi 

     Sugbon nitori eje eje Re 

     B'O si ti pe mi pe ki nwa 

     Olugbala, mo de.


2.  Bi mo ti ri, laiduro pe 

     Mo fe k'okan mi mo toto 

     Sodo Re t'o le we mi mo 

     Olugbala, mo de.


3.  Bi mo ti ri, b’o tile je 

     Ija lode, ija ninu 

     Eru lode, eru ninu 

     Olugbala, mo de.


4.  Bi mo ti ri: osi, are 

     Mo si nwa imularada 

     Iwo lo le s'awotan mi 

     Olugbala, mo de.


5.  Bi mo ti ri: ‘Wo o gba mi 

     ‘Wo o gba mi towo-tese 

     “Tori mo gba ‘leri Re gbo 

     Olugbala, mo de.


5.  Bi mo ti ri: Ife Tire

     Lo sete mi patapata

     Mo di Tire, Tire nikan 

     Olugbala, mo de.  Amin

English »

Update Hymn