HYMN 236

C.M.s.187 H.C.117 t.S 43 (FE 256) ss 97
"Ba mi yo, mo ri aguntan mi." - Luku 15:6
Tune: lpile ti Jesu fi lele



1.  MOKANDILOGORUN dubule je

     Labe oji nin’agbo 

     Sugbon okan je lo or'oke 

     Jina s’ile ilekun wura 

     Jina rere l'or oke sisa 

     Jina rere s‘OIus’aguntan.


2.  'Mokandilogorun Tire leyi 

     Jesu, nwon ko ha to fun O? 

     Olus’agutan dahun, 'Temi yi, 

     Ti sako lodo mi

     B'ona tile ri palapala

     Ngo w’aginju lo w'agutan mi.


3.  Okan nin‘ awon t"ara pada 

     Ko mo jinjin omi na

     Ati duru oru ti Jesu koja 

     K’o to r‘agutan re he 

     L’aginju rere I’o gbo 'gbe re 

     O ti ri tan, o si t ku tan.


4.  Nibo n’iro eje ni ti wa

     To fona or‘oke han?

     ‘A ta sile f’enikan t’o sako 

     K’Olusagutan to mu pada 

     Jesu, kil' o gun owo Re be? 

     ‘Egun pupo l'o gun mi nibe.


5.  Sugbon ni gbogbo pori oke 

     At l'ori apata

     lgbe ta l’ooke orun wipe 

     “Yo, mo r’agutan ni he" 

     Y’ite ka l’awon angel ngba 

     'Yo, Jesu m‘ohun Tire pada.  Amin

English »

Update Hymn