HYMN 229

O.t.S. 57. 8s. 7s (FE 249)
"Nwon igbati aiye yio wa, igba orun 
on ojo ati osan ati oru ki yio 
dekun." - Gen. 8:22
Tune: Okan mi yin Oba orun



1.  OLOWA alafia wa, 

     L’opase t'odun yipo 

     Awa omo Re wa dupe 

     F'odun titun t’a bere 

     Yin Oluwa! Yin Oluwn 

     Oba nla t'O da wa si.


2.  A dupe fun ipamo wa 

     Ni odun ti o koja

     A mbebe iranlowo Re, 

    Fun gbogbo wa lodun yi 

    Jek’ljo wa, jek’ljo wa 

    Ma dagba ninu Kristi.


3.  K’agba k'o mura lati sin 

     Lokan kan ni odun yi 

     K'awon omode k‘o mura

     Lati saferi Jesu 

     K’alafia, k’alafia 

     K’o se ade odun yi.


4.  K‘Emi Mimo lat’ oke wa 

     Ba le wa ni odun yi

     Ki Alufa at’Oluko 

     Pelu gbogbo Ijo wa

     Mura giri, Mura giri 

     Lati Josin f'Oluwa.  Amin

English »

Update Hymn