HYMN 228

11.11.11.11
Tune: "E ma tesiwaju"



1.  N'bere odun yi, odun titun yi 

     Oro itunu de, ti nle eru lo

     Ohun keje jeje, ti Baba orun 

     Ododo l’oro na, ti nm'okan wa yo.

Egbe:  E ma tesiwaju, 

           omo imole

           Oro Re ko le ye, 

           O nduro titi.


2.  Ma beru ‘loro na, Mo wa pelu yin 

     Emi n’iranwo yin at’agbara yin 

     Emi y'o di yin mu, li owo ‘tun mi 

     Mo pe yin, mo yan yin, lati je

     temi titi.

Egbe:  E ma tesiwaju..


3.   Fun opo odun ti mbe niwaju wa

      Opo ni ipese t'awon seleri

      lpese f‘alaini f'awon elese

      F'awn t'a npon loju, fun alailera wa. 

Egbe:  E ma tesiwaju..


4.  Ko je fi wa sile, ko si ni ko wa 

     Majemu Re daju ti ko le ye Iae

     A ro mo ‘leri yi, eru ko ba wa 

    Olorun wa ti to, fun odun ti mbo.

Egbe:  E ma tesiwaju, 

           omo imole

           Oro Re ko le ye, 

           O nduro titi.  Amin

English »

Update Hymn