HYMN 222

C.M.S 96 C.M (FE 241)
"Je ki ise Re ki o han si awon omo
odo Re" - Ps. 90:16



1.  OLORUN at' ireti mi 

     Oro Re l‘onje mi

     Owo Re gbe mi ro l’ewe 

     Ati l’odomode.


2.  Sibe mo rohun iyanu 

     ‘O nse ni ododun 

     Mo fi ojo mi ti o ku 

     S’iso Tire nikan.


3.  Ma ko mi, nigba‘agbara ye 

     Ti ewu ba bo mi

     Ki ogo Re ran yi mi ka 

     Nigbati mo ba ku.  Amin

English »

Update Hymn