HYMN 220

1.  ORE-OFE Baba, ati t‘Omo Re 

     Ore-ofe Emi, metalokan lai

     My iyin wa funwa ati imole

     O le okunkun lo, o nm‘okan wa yo.

Egbe:  Ore-Ofe Olorun si wa iyanu ni 

           Ope ore-ofe Re wa nibi gbogbo 

           Ore-ofe nla ti' nfo gbogbo eda mo 

           Wa to ebun ofe wo, ore-ofe nla.


2.  Nibiti ese po, or'ofe njoba 

     Itan ‘yanu l‘eyi, to sowon pupo 

     Mase so ‘reti nu, ore‐ofe nsan 

     O ga ju orun lo, o jin ju okun.


3.  A nf‘ ore-ore yi, lo gbogb’enia 

    We, iwo t'eru, y’o gbe won fun 

    Enika to wa, a ki y’o tanu 

    Yio fe o lofe, ma siyemeji.  Amin

English »

Update Hymn