HYMN 216

SS 455 (FE 235)
"Ma tan, Iwa lrawo" - Ifi. 22:16



1.  MA tan, Irawo didan, 

     Lat’ Ile Re loke;

     Ma fi ‘feran Baba han, 

     N'nu titan didan Re. 

Egbe:  Ma tan, ma tan,

           Iwo lrawo didan, 

           Ma tan, ma tan,

           Iwo Irawo didan.


2.  Ma tan, Irawo Ogo, 

     A gboju wa si O;

    Li oke awosanma, 

    Awa nri ‘tansan Re. 

Egbe:  Ma tan, ma tan...


3.  Ma tan, ‘wo ti ki paro, 

     Ko si s’amona wa; 

     Sibi t’imole ayo,

     Ti ko lopin gbe wa.

Egbe:  Ma tan, ma tan...


4.  ‘Gba ba si d’orun pelu, 

     Awon t’arapada; 

     k’a wa pelu Re n'nu Ogo, 

     Le ma tan titi lai.

Egbe:  Ma tan, ma tan,

           Iwo lrawo didan, 

           Ma tan, ma tan,

           Iwo Irawo didan.  Amin

English »

Update Hymn