HYMN 206

C.M.S. 81 H.C. 87. 7s. (FE 225) 
"Nitori a bi omo kan fun wa"
- Isa. 9:6



1.  GBO, eda orun nkorin: 

     “Ogo fun Oba t'a bi“ 

     “Alafia laiye yi,

     Olorun ba wa laja, 

     Gbogbo eda nde layo; 

     Dapo mo hiho orun;

     W‘ Alade Alafia! 

     Wo, Orun ododo de.


2.  O bo'go Re s‘apakan; 

     A bi k’enia ma ku; 

     Abi k‘ o’gb’enia ro;

     A bi k‘ o le tun wa bi. 

     Wa, ireti enia

     Se ile Re ninu wa 

     N'de, lru omobinrin 

     Bori esu ninu wa.


3.  Pa aworan Adam run;

     F' aworun Re s’ipo re;

     Jo masai f’ Emi Re kun, 

     Okan gbogbo’ onigbagbo, 

     “Ogo fun Oba t’ a bi” 

     Jeki gbogbo wa gberin; 

     "Alafia laiye yi"

     Olorun ba wa laja.  Amin

English »

Update Hymn