HYMN 205

1.  TAN ihin na kale, jakejado aiye 

     K'awon ti eru npa

     Mo pe igbala de

     K‘awon t’ise ti Krist’

     So ihin ayo na.

Egbe:  Olutunu ti de, Olutunu ti de 

            Emi Iat’ oke wa, ileri

            Baba wa

            Tan ihin na kale, jakejado aiye 

            Olutunu ti de.


2.  Oba awon oba, wa f 'iwosan fun wa 

     O wa ja ide wa, O mu igbala wa 

     K‘olukuluku wa, korin isegun pe.

Egbe:  Olutunu ti de...


3.  lfe iyanu nla, a! mba rohin na 

     Fun gbogbo enia, ehun or‘ofe Re 

     Emi omo egbe, di omo igbala. 

Egbe:  Olutunu ti de...


4.  Gbe orin ‘yin soke 

     s'olurapada wa

     K‘awon mimo l‘oke

     Jumo ba wa gberin

     Yin ife re titi, ife ti ko le ku.

Egbe:  Olutunu ti de, Olutunu ti de 

            Emi Iat’ oke wa, ileri

            Baba wa

            Tan ihin na kale, jakejado aiye 

            Olutunu ti de.  Amin

English »

Update Hymn