HYMN 200

H.C 91 87. 8.7.8. 7.8.7
“Awa wa lati foribale fun u" 
-Matt. 2:2



1.  ENYIN Angel’ l’orun ogo, 

     To yi gbogbo aiye ka;

     E ti korin dida aiye,

     E so ti‘ ibi Messia;

Egbe:  E wa josin, e wa josin, 

            Fun Kristi Oba titun.


2.  Enyin Oluso - agutan, 

     Ti nso eran nyin loru, 

     Emmanueli wa ti de, 

     Irawo Omo na ntan.

Egbe:  E wa josin...


3.  Eyin Oluso-aguntan,

     Ti n so eran yin loru

     Emmanueli wa ti de,

     Irawo omo naa n tan.

Egbe:  E wa josin...


4.  Elese 'wo alaironu,

     Elebi ati egbe, 

     Ododo Olorun duro, 

     Anu npe o, pa ‘wa da.

Egbe:  E wa josin...


5.  Gbogbo eda e fo f'ayo, 

     Jesu Olugbala de, 

     Anfani miran ko si mo, 

     B’eyi ba fo yin koja.

Egbe:  E wa josin, e wa josin, 

            Fun Kristi Oba titun.  Amin

English »

Update Hymn