HYMN 193

C.M.S 65 t. H.C 14 L.M (FE 211)
"Awa mo pe Omo Olorun de" 
- I John 5:20



1.  ONIDAJO na de, O de! 

     Beni ‘pe keje ti ndun nwi 

     Manamana nko, ara nsan 

     Onigbagbo y’o ti yo to!


2.  A ngbo, Angel orun nwipe 

     Jesu Oluwa wa d‘ade 

     Ore’Ofe l’On fi damure

     Ogo l‘On fi s'oso boju.


3.  ‘Wo sokale l’or‘ite Re

     O gba ijoba fun ‘ra Re

     Ijoba gbogbo gba Tire 

     Nwon gba b’Oluwa t’o segun.


4.  Gbogbo ara orun, e ho 

     At’ enia Oluwa wa,

     Oga ogo t’o gba ola

     Yio joba lai ati lai.  Amin

English »

Update Hymn