HYMN 191

C.M.S. 70 t,  H.C 73. 8s. 7s 4 
(FE 209)



1.  WO! Oluwa l'awosanma 

     O mbo l'ogo l'ola Re, 

     Enit‘ a pa fun elese

     Mbo pelu Angeli Re 

     Halleluyah!

     Halleluyah!


2.  Gbogbo eda, wa wo Jesu

     Aso ogo I'a wo fun

     Awon t‘o gan, a won t'o pa 

     T‘o kan mo Agbelebu

     Won o sokun

     Bi nwon ba ri Oluwa.


3.  Erekusu. okun, Oke, 

     Orun, aiye, a fo lo

     Awon t‘o ko a da nwon ru 

     Nigbati nwon gb'ohun Re 

     Wa s'idajo

     Wa s‘idajo, wa kalo!


4.  lrapada t'a ti nreti

     O de pelu ogo nla 

     Awon ti a gan pelu re, 

    Yio pade Re loj‘orun! 

    Halleluyah!

    Ojo Olugbala de.  Amin

English »

Update Hymn