HYMN 19

(FE 36)
C.M.S 15, H.C 20, 10s
"Ba wa duro, nitori o di oju ale" 
- Luku 24:29


1.  WA ba mi gbe Ale fere le tan,

     Okunkun nsu, Oluwa ba mi gbe 

     Bi oluranlowo miran ba ye 

     lranwo alaini, wa ba mi gbe!


2.  Ojo aiye mi nsare lo s’opin 

     Ayo aiye nkun, ogo re nwo mi, 

     Ayida at’ibaje ni mo nri

    Wo ti ki yipada, wa ba mi gbe.


3.  Ma wa l'eru b‘Oba awon Oba, 

     Sugbon ki O ma bo b‘oninu re 

     Ki o si ma kanu fun egbe mi 

     Wa, ore elese, wa ba mi gbe!


4.  Mo nfe O ri, ni wakati gbogbo 

     Kil'o le segun Esu b‘ore Re? 

     Tal‘o le se amona mi bi Re? 

     N'nu 'banuje at' ayo ba mi gbe!


5.  Pelu 'bukun Re, eru ko ba mi
 
     lbi ko wuwo, ekun ko koro

     Oro iku da? ‘segun isa da

     Ngo segun sibe, b'lwo ba mi gbe.


6.  Wa ba mi gbe ni wakati iku 

     Se 'mole mi, si toka si orun

     B'aiye ti nkoja, k'ile orun mo

     Ni yiye, ni kiku, wa ba wa gbe.  Amin

English »

Update Hymn