HYMN 183

CM.S 50 O. t H. C. 141 7s (FE 201)
"Idajo nla" - Juda 6



1.  OJO 'dajo on 'binu

     Ojo ti Jesu pa ni 

     Gbobgo a so n'jo na!


2.  Kikan n'ipe o ma dun 

     Isa oku yio si,

     Gbogbo oku y'o dide.


3.  Iku papa y'o diji

     Eda gbogbo y'o dide

     Lati jipe Olorun.


4.  A o si Iwe sile

     A o si ka ninu re

    Fun 'dajo t'o ku t'aye.


5.  Onidajo Ododo

     Jo w'ese mi gbogbo nu 

     K'ojo siro na to de.  Amin 
 

English »

Update Hymn