HYMN 177

D.S.M



1.  IJO ti nduro pe

     Lati ri Oluwa

     O si wa bakan na sibe 

     Ko s‘alabaro fun 

     Odun nyi lu odun

     Ojo ngori ojo

     Sibe lairi Oluwa re

     O wa ninu ofo 

     Ma bo, Jesu ma bo!


2.  Awon mimo l‘aiye

     Opo won l‘oti ku

     Bi won si ti nlo l’okankan 

     L’a te won gbe ‘ra won

     A te won lati sun

     Ki se ainireti

     A te won lati r'eju ni 

     K'ile ogo to mo 

     Ma bo, Jesu mabo!


3.  Awon ola npo si

     Abgara esu nga

     Ogun ngbona, igbagbo nku 

     lfe si di tutu

     Y’o ti pe to Baba

     Oloto Olore

     Wo ki y’o koya omije 

     At’eje Ijo Re

    Ma bo Jesu ma bo!


4.  A nfe gbo ohun Re

     A nfe f'oju kan O 

    K‘a le gba ade at' ogo 

    B‘a ti ngha ore Re 

    Jo, wa m‘ese kuro

    A t‘egun at'eri

    K‘o si so aye osi yi

    D‘aye rere Tire

    Ma bo, Jesu ma bo.  Amin

English »

Update Hymn