HYMN 152

CM.147, t.H.C 400 C.M. (FE 170) 
"Woli nIa dide li arin wa” - Luku 7:16



1.  'WO, owon Olurapada 

     A fe ma gburo Re

     Ko s'orin bi oruko Re, 

     T'o le dun t'abo re.


2.  A! a ba le ma gbohun Re, 

     L’anu soro si wa,

     Nin’ Alufa wa l’a o yo 

     Melkisedek giga.


3.  Jesu ni y’o se orin wa, 

     Nigbat’ a wa l‘aiye

     A o korin ife Jesu 

    'Gba nkan gbogbo baje


4.  Nigba 'ba yo soke lohun

     Pelu 'jo, eni Re

     'Gbana a o korin kikan

     Kristi'mi y'o j'orin wa.  Amin

English »

Update Hymn