HYMN 151

C.M.S 553, H.C 568 S.M (FE169) 
“Nwon si nko orin Mose, iranse 
Olorun, ati orin Od'agutan" - Ifi. 15:3



1.  JI! ko orin Mose

     At t'Odagutan

     Ji gbogbo okan at‘ahon 

     Ki nwon yin Oluwa.


2.  Korin ti iku re,

     Korin ajinde Re, 

     Korin b’o ti mbebe loke 

     F’ese awon t'O ru.


3.  Enyin ero l'ona

     E korin b’e ti nlo

     E yo ninu Od’agutan 

     Ninu Kristi Oba.


4.  E fe gbo k'O wipe 

     ‘Alabukun, e wa"

     On fere pe nyin lo kuro 

     K’O mu Tire lo ‘le.


5.  Nibe l’aokorin 

     lyin Re ailopin

     Orun y’o si gbe ‘rin Mose 

     Ati t’Od‘agutan.  Amin

English »

Update Hymn