HYMN 142

1.  Eyin Oba ogo, On ni Olorun 

     Yin I fun se yanu ti O fi han

     O wa pel’ awon ero mimo l'ona 

     O si je imole won l'osan l‘orun.

Egbe:  Eyin angel didan lu duru wura

            Ki gbogbo nyin juba t'e nwo oju Re 

            Ni gbogbo 'joba Re, b'aye ti nyi lo 

            Ise Re y'o ma yin

            Ise Re y'o ma yin

            Fi ibukun fun Oluwa okan mi.


2.  E yin fun ‘rapada, ti gbogbo okan 

     E yin fun orisun lmularada

     Fun inu rere ati itoju Re 

     Fun'daniloju pe O ngbo adura. 

Egbe:  Eyin angel didan lu duru...


3.  Eyin fun idanwo, bi okun ife

     T'o aso wa po mo awon ohun orun 

     Fun ‘gbagbo ti nsegun ‘reti ti ki sa 

     Fun ile Ogo t'O ti pese fun wa. 

Egbe:  Eyin angel didan lu duru wura

            Ki gbogbo nyin juba t'e nwo oju Re 

            Ni gbogbo 'joba Re, b'aye ti nyi lo 

            Ise Re y'o ma yin

            Ise Re y'o ma yin

            Fi ibukun fun Oluwa okan mi.  Amin

English »

Update Hymn