HYMN 136

(FE 153)
Tune: F’eru re f’a fefe S.M.



1.  F'IBUKUN f’Oluwa!

     K’okan at’inu mi,

     Pel'ahon mi yin Oko Re, 

     Fun gbogbo ore Re.


2.  F’ibukun f’Oluwa 

     Okan mi ma gbagbe 

     Lati s’ope, Iati f'iyin 

     Fun opo anu Re.


3.  O f'ese re ji O 

     O mu ‘rora re lo

     O wo gbogbo arun re san, 

     O so o d’atunbi.


4.  O f' onje f ‘alaini 

     lsimi f’ojiya;

     Y'o se ‘dajo agberaga 

     Y’o gbeja alaise.


5.  O f‘ise 'yanu Re,

     Han, lat’ owo Mose 

     Sugbon oto at’ore Re

     L'o fi ran Omo Re.  Amin

English »

Update Hymn