HYMN 131

Tune: CM



1.  A k’orin s’Omo Olorun 

Odagutan t’a pa

Ti orun ati aye mbo 

T'O ye lati joba.


2.  Si O l’awon Angeli nke 

     L'ekun gbogbo orun 

     Mimo mimo, mim'Olorun 

     T'ogo at’om'ogun.


3.  ljo Re li aye dapo 

     Lati ma kepe O 

     Didan Olanlan Olorun 

     T'O l‘agbara gbogbo.


4.  Larin won ni gbogbo wa nfe

     Lai yin eje re

     Joba l’aye ati l'orun

     Wo Omo Olorun.  Amin

English »

Update Hymn